Yoruba Studies Review (Dec 2021)

Ìtúpalẹ ̀ Àṣàyàn Oríkì Ẹranko

  • Olúfúnmiláyọ ̀ Tèmítọpẹ Ajàyí ́,
  • Olusola George Ajibade

DOI
https://doi.org/10.32473/ysr.v6i1.130099
Journal volume & issue
Vol. 6, no. 1
pp. 1 – 21

Abstract

Read online

Àwọn Yorùbá fé ràn oríkì púpo ̣ ̀ , wo ̣ ́ n sì gbádùn láti máa lò ó nígbà gbogbo ̣ tí ohun tí ó jẹ mó ọn bá wáyé. Ní ilé ayé, oríṣiríṣi ni iṣe ̣ ́ ọwo ̣ ́ Ẹle ̣ ́ dàá, oríṣiríṣi ̣ sì ni è dá ọwo ̣ ́ rẹ ̀ . Bí Ẹle ̣ ́ dàá ṣe dá ayé tí ó dá ohun tí ó ń mí náà ni ó dá ewéko, ̣ igi igbó, ẹyẹ, ejò afàyàfà ẹranko àti bé ẹ̀ bẹ ́ ẹ̀ lọ. Nínú ohun gbogbo tí Ọlo ̣ ́ run dá ̣ kò sí ohun tí Yorùbá kò fún ní oríkì. Bí Yorùbá ṣe ní oríkì fún ènìyàn kò ọ ̀ kan ̣ àti àwọn orílè kọ ̀ ọ ̀ kan náà ni wo ̣ ́ n ní oríkì fún àwọn ẹranko èyí tí ó ń ṣe àpè ̣ - júwe wọn gé gẹ ́ bí ìrísí wọn, ìṣesí wọn àti ìhùwàsí wọn, ipò tí o ̣ ̀ kọ ̀ ọ ̀ kan wọn ̣ wà láàrin ẹranko ẹlẹgbé wọn àti ìgbàgbo ̣ ̣ ́ àwọn ènìyàn àwùjọ nípa wọn. Oríkì àwọn ẹranko bíi Kìnnìún, Ẹkùn, Erin, Àgbò nrín, Ìkookò, Ko ̣ ̀ lọ ̀ kọ ̀ lọ ̀ , Ẹfo ̣ ̀ n àti ̣ Ẹtà ni a ṣe ìtúpalè rẹ ̀ nínú iṣe ̣ ́ àpile ̣ ̀ kọ yìí láti ṣàfihàn èrò àti ìgbàgbo ̣ ́ àwọn ̣ Yorùbá nípa ẹranko. A ṣe àkójọpò oríkì àwọn àṣàyàn ẹranko tí a gbà síle ̣ ̀ bí wo ̣ ́ n ṣe jẹ yọ nínú ̣ ìjálá àti ìrèmò jé tó je ̣ ̣ ́ lítíréṣò alohùn tí a mo ̣ ̀ mo ̣ ́ àwọn ọdẹ. Ìtúpale ̣ ̀ aláwòmo ̣ ́ ̣ àkóónú (content analysis) ni a ṣe sí àkójọpò -èdè fáye ̣ ̀ wò tí a gbà síle ̣ ̀ láti ẹnu ̣ àwọn ọdẹ. A lérò pé iṣé iwádìí yìí yóò fi òye àti ìmo ̣ ̀ kún ìmo ̣ ̀ lórí ohun tí ̣ ẹranko jé , àfihàn èrò àti ìgbàgbo ̣ ́ àwọn Yorùbá nípa ẹranko àti ipa tí àwọn ̣ ẹranko igbó ń kó ní ìgbésí ayé wọn.