Yoruba Studies Review (Dec 2021)

Kíkọ́ èdè Yorùbá Gẹ́gẹ́ bí Èdè Abínibí: Àkóónú àti ọgbọ́n Ìkọ́ni

  • Solomon Olanrewaju Makinde

Journal volume & issue
Vol. 1, no. 2

Abstract

Read online

Ninu apileko yii, mo salaye ni ekunrere lori akoonu, ogbon-ikoni, ogbon iseto, ati ilana ayewo fun awon oluko ti won n ko ede Yoruba gege bi ede abinibi. Mo safiwe iyato ti o wa laarin akitiyan awon oluko ede Yoruba gege bi ede abinibi ati awon oluko ti won n ko ede Yoruba gebe bi ede ajoji tabi ede akokunteni.